Se e ni ise sha?Ok,e je ka start talking.......Emi ni Stella oh...
Ise loogun ise
Ise loogun ise
Mura sise ore e mi
Ise la fi n de ni giga
Bi ako ba re mi feyinti
Bi o le laari, bi ako ba re ni gbekele
Atera mo se e ni,
Iya re le lowo lowo,
Baba re le lesin leekan
Bo ba gboju le won
O te tan ni mo wi fun e
O un ti a ko ba jiya fun
Se kii lee tojo
Oun taa ba fara sise fun
Niipe lowo e ni
Apa lara, igunpa ni ye kan
Bi a ye fe o loni, boo ba lowo lowo
Ni won ma fe o lola
Eko situn nsoni doga
Mura ki o ko tire daradara
Iya nbe fomo ti ko gbon
Ekun nbe fomo tin sa kiri
Ma fowuro sere ore mi
Mura si ise ojo nlo.
Gegebi ewi ti mo ko saaju bi ako ba re ni feyinti, ka tera mose e ni. Kosi awijare fun enikeni lati wa ninu ise sibe. Atelewo eni ki tan ni je. Mura sise ore e mi, ise lafi n de ni giga.
It's moral on hard work, whatever your hands can do, do it diligently. There is dignity in labour..
Olori Orente
😂😂😂😂😂😂😂
ReplyDeleteStelllaaaaaaa iru aworan wo leleyi???
Olori, I will send beloved a mail to request for your contact as per tailor thing.
DeleteIse o kin pa eyan "ise"(E yen ni omo labe) lo payan.
DeleteMo ni ki n beere ni, wipe se iwo abi stella lo fi aworan yen si?
DeleteSigidi lori ewi ise? Mo ri tuntun.
O kare Olori.
Oro ijinle ti awa odo aye ode oni o fe gbo mo ni eleyii.
Wiriwiri la n wa owo.
A ti gbagbe wipe oun ti a koba sise fun ki n pe lowo eni.
Intro stella yen baadi gan
ReplyDeleteHmmmm.... I can see that Stell is bored
ReplyDeleteAnthem ogun state :
ReplyDeleteIse ya
Omoogun Ise ya,Omo rere kii sa se, Omoogun kii se ole,
Ebeere gbe eru o. Oluwa nbe funwa ete ara mo Ise o, Ise yaaaa
Ise ya ohhh🎼🎼🎼🎼🎼🎼🎼
DeleteMoral on hardworking and you're using pictures of demonic forces?
ReplyDeleteThat kain hard work eh
Yara sise re ore mi. Igba gbo laisise of ni. Please guy I want to know if it's normal, I bath more than 4× when am on my period and I clean the house, do all sorts of arrangement if I visit you I will help you dust any dusty thing or help wash any dirty thing around. Please am I normal. I need help.
ReplyDeleteyes my dear you are very normal.
DeleteWhat you described is exactly me during my 3rd trimester, it happened during my 2 pregnancies.
So I believe that it is normal.
You don't need help please.
You don't need any help
DeleteThat's me you described 👆
Abeg am interested in this write up but I don’t know what it means. I be omo Igbo o. Can someone explain?
ReplyDeletePrettiest Rosie darling, I am talking about hardwork.....Whatever your hands find doing,do it.
DeleteWe might want a big offer, but for the moment do something legit to keep body and soul....
Awww! Thanks for explaining dearie, now I understand... Even the Bible says do not despise the days of humble beginnings
DeleteIs it talking about idol worshipping because those images looks like idols. May nobody laugh at me o. Lol...
ReplyDeleteDon't mind Sdk,don't know where she got the image????
DeleteOlori, omo rere bi iyan... child like pounded yam 🤣🤣🤣🤣 hope I got it?
DeleteStella ooooh.. e je ka start talking...lmao
ReplyDeleteOlori Orente, e ku ise opolo ma.
Eseun oh
DeleteAtelowo ẹni ní kí tani je. Kosi ẹnikẹ́ni tí ó ṣe gbójú lè ayafi Ọlọhun nikan. Ẹ ja ká múra sì ìṣe owó wá. Ó káre Olórí Orente. Oluwa a túbọ̀ má sọ agbára ẹ di otun.
ReplyDeleteEseun pupo
DeleteSigidi ati ise ko lo rara. Ise ni cure to poverty.
ReplyDeleteE je ki a mura si ise, ki a si fi owuro wa sise ki a ma a ba fi asale wa jiya.
Toor! Ire o.
Olori, e ku kiko. E seun wa.
Omo re bi custard
DeleteAdupe oh
Ni ona miran, a lee lo sigidi lati shee apejuwe ise owo, awon tii won ngbe sigidi ati awon nkan miran bi awon nkan tii a lee fii mu inu Ile waa rewa laa n pee ni agbegi leere. Aa npe won nii kafinta layee odee oni " Kaa finn kaa taaa". Itumo Kafintaa (Carpenter) niyen. Olori ee kuu ise o.
DeleteMo ranti ewi yi, ojojumo laman ka ni gba tia wan kekere. Ooto oro 'ise ni ogun ise'.
ReplyDeleteOlori ku ise na, Oluwa a tubo ma so agbara dotun.
Eseun pupo
DeleteBeeni oh, ise loogun ise.
ReplyDeleteThank God I read for daytime...principalities and powers
ReplyDelete