Ilu yi fidikale si apa ila oorun odo Ogun. Lara awon oun ti a le ri ra loja won ni epo pupa, igi gedu, roba, isu, iresi, agbado, owu, ori ati bee be lo. Idi ti won fi n pe e ni Abeokuta ni wi pe abe ori oke Olumo ni ilu naa wa.
Oju ona reluwe wa, ti o lo lati Eko si Abeokuta, o si je kilomita merindinlogorin(77). Won se oju ona reluwe yi ni 1899. Awon ona miiran ti o tun wo Abeokuta ni Ibadan, Ilaro, Sagamu, Iseyin....
Sodeke ni o te ilu Abeokuta do ni 1825. Gege bi ibi aabo lowo awon olowo eru lati Dahomey ati Ibadan. Awon ara Egba ni won koko tedo si Abeokuta.
Abeokuta di Olu ilu ipinle Ogun ni odun 1976. Abeokuta je ilu ti a mo odi yi ka, lara re si wa titi do ni. Ake ni Alake,ni oba won ngbe. Ile iwe giga ti yunifasiti ise agbe wa ni Abeokuta. A da sile ni 1988.
Di e lara awon gbajugbaja omo Abeokuta ni.......
Olufela Anikulapo Kuti
Efunroye Tinubu
MKO Abiola
Olusegun Obasanjo
Jimi Solanke
Funmilayo Ransome –Kuti
Bola Ajibola
Oloye Akintola Williams
Wole Soyinka
Ebenezer obey
Dimeji Bankole
Sir Shina Peter
Olusegun Osoba
Kini Awon ohun daradara ti ale so nipa Abeokuta?????
We are talking about Abeokuta in Ogun state and the Important persons who hail from there.....
Olori Orente
Oju ona reluwe wa, ti o lo lati Eko si Abeokuta, o si je kilomita merindinlogorin(77). Won se oju ona reluwe yi ni 1899. Awon ona miiran ti o tun wo Abeokuta ni Ibadan, Ilaro, Sagamu, Iseyin....
Sodeke ni o te ilu Abeokuta do ni 1825. Gege bi ibi aabo lowo awon olowo eru lati Dahomey ati Ibadan. Awon ara Egba ni won koko tedo si Abeokuta.
Abeokuta di Olu ilu ipinle Ogun ni odun 1976. Abeokuta je ilu ti a mo odi yi ka, lara re si wa titi do ni. Ake ni Alake,ni oba won ngbe. Ile iwe giga ti yunifasiti ise agbe wa ni Abeokuta. A da sile ni 1988.
Di e lara awon gbajugbaja omo Abeokuta ni.......
Olufela Anikulapo Kuti
Efunroye Tinubu
MKO Abiola
Olusegun Obasanjo
Jimi Solanke
Funmilayo Ransome –Kuti
Bola Ajibola
Oloye Akintola Williams
Wole Soyinka
Ebenezer obey
Dimeji Bankole
Sir Shina Peter
Olusegun Osoba
Kini Awon ohun daradara ti ale so nipa Abeokuta?????
We are talking about Abeokuta in Ogun state and the Important persons who hail from there.....
Olori Orente
Where is my name? Awa l'omo abeokuta
ReplyDeleteilu rere ilu olola
nibe no bi Fehintola si
Egba omo lisabi
ππππ
Deleteeku orire....
DeleteAbeokuta tobi sugbon oja tita ko ya rara nitori ko si awon ile ise nla nla nibe bii Agbara,Sango ati bee bee lo.
DeleteGomina Ipinle Ogun, SIA ni paapaa julo le fi ara han bi ore ara ilu sugbon ogbontarigi omo ita ponbele ni. Bi o ti n ge owo osise, bee ni ko san owo ifehinti fun awon to ti fehinti ninu ise ijoba ati bee bee lo.
Ina kii wa deedee, omi ti di ohun igbagbe, ohun gbogbo lo won bi oju.
A n ra owo ebe si gbogbo awon otokulu,ti won ni eti Gomina wa, lati baa soro nitori iya n je ara ilu.
E seun.
Lori oke o'un petele Ibe l'agbe bi mi o Ibe l'agbe to mi d'agba oo Ile ominira
ReplyDeleteChorus: Maa yo, maa yo, maa yo o; l'Ori Olumo; Maa yo, maa yo, maa yo o; l'Ori Olumo
Abeokuta ilu Egba N ko ni gbagbe e re N o gbe o l'eke okan mi Bii ilu odo oya Emi o f'Abeokuta sogo N o duro l'ori Olumo Maayo l'oruko Egba ooo Emi omoo Lisabi E e
Chorus: Maa yo, maa yo, maa yo o; l'Ori Olumo; Maa yo, maa yo, maa yo o; l'Ori Olumo
Emi o maayo l'ori Olumo Emi o s'ogoo yi l'okan mi Wipe ilu olokiki o L'awa Egba n gbe
Chorus: Maa yo, maa yo, maa yo o; l'Ori Olumo; Maa yo, maa yo, maa yo o; l'Ori Olumo
Egba ile ibe nigbagbo ti se wa, Egba ile ibe nigbagbo ti se wa
Awa Egba lo ni jesu o
Awa lo mo abeokuta, ilu rere ilu olola
ilu to duro lase oluwa, Egba omo lisabi.
ππππππ
DeleteEgba re wa,i love this town.
DeleteAwa lomo Abeokuta, ilu rere, ilu olola. Inumi dun lati je omo Egba.
ReplyDeleteEgba re waπππ
DeleteEku dede iwoyi oh eyin ara ile, Olori Orente, e seun gan fun alaye ti e se nipa Ilu olola ati olokiki julo ni ile adulawo, ilu mi, ilu re ati ilu gbogbo wa ti n se Abeokuta. Ilu ti atedo si abe apata Olumo. Afikun te mi ni wipe, ilu yi gangan ni olaju ti bere ati wipe ibe gan ni eko awon oyinbo ti bere. Awon nkan meremere si wa nibe pelu. Olori eku ogbon oh, Olohun yi o bukun imo ati oye yin oh.
ReplyDeleteJkool omo iya mi
DeleteEku ojo meta,Amin oh
Abeokuta a nice place to live if you are the quiet type with no close relatives in town. But.... the people ehn..they can so like to do jazz.
ReplyDeleteMo ni'fe Lati lo si apata olumo ni ojo kan. Ede egba ni agbara pupo. Mo feran kii ma gbo ede won. Shey oto ni wipe Γ²gΓΉn (charm) po ni ipile Ogun?
ReplyDeleteE ku ise Iyaafin Orete
Eyan MI Eshey gan
DeleteLooto ni, ogun po
Prudent maa nife laati mu e lo si olumo rock by end of this month
DeleteGhen ghen ghen ghen! E se o Sealord
DeletePrudent temi nikan oya ooo ππππ
DeleteAwon omo Abeokuta maa nba ara won ja lopolopo. Idile Obasanjo ati Idile Fela ko le ri ara won si oju di oni.
ReplyDeleteOlori,ku ise.
Adupe ooo
DeleteOruko oko mi daa? Omo Abeokuta gidi ni....
ReplyDeleteEku ise omo iya. See ise n'lo de de?
Adupe Eyan mi
DeleteMo gbagbe oruko won niπππ
Emabinu
I am so proud of abeokuta so much luv for ogun state. Representing for life
ReplyDeleteThere is this song sang by Sir shina Peters "egba ile ibe l'ola ju tii beere" I love the song
ReplyDeleteI love the song too brother
DeleteHow's work??
Work is cool but lagos is no joke
DeleteMo feran awΓ²n omo Γ¨gba gidi gΓ Γ n.....amo ilΓΉ Ekiti ni emi tiwΓ .
ReplyDeleteΓweso oo dede omo egbaππ
Abeokuta =under stone
ReplyDeleteI love the town. Quiet and very peaceful. Its a cool place to be. But the place has very terrible inner roads. Some are almost not motorable especially during the rainy season. Their governor just focused on the express (major) roads and has totally ignored the inner roads. For example, that Adigbe-Obada-Lagos road;a greater part of that road is so bad and nothing is being done about it.
ReplyDeleteIn fact, not just the roads, so many things are not working but people can't even protest before they get killed or injured by thugs!
DeleteAbeokuta, the Seat of "Internet Workers"π
Civilization in nigeria started from abeokuta.
ReplyDeleteThe very first state that will have state anthem.egba is too much with lovely song.
ReplyDelete