Olori Orente ti pada wa...sebi oro yi o lagbara!..Emi ni Stella,mon she intro,toripe Olori o mo se intro....Mon shake my head no ni..LMAO!
( The ants do not truly like the cornstalk,
so is the love of other people minimal)
2.Epe ibinu ko pa odi
(Cursing a deaf in anger has no effect)
3.Ero ona ni royin oka to gbo
(Passers-by are the first to bring the news that the corn is ripe)
4.Eti baba nile, eti baba l'oko;eniyan ni i je be
(Father hears everything because people tell him)
5.Ewure ti n je alubosa,oju ni i nkan; kini won yoo fi se
( A goat that eats onions is just in a hurry,is that not the ingredient with which it will be cooked?)
6.Ewure wo alapata bi ko ku
( The goat looks at the butcher and wished him dead)
7.Eyi ko t'ofo,eyi ko t'ofo; fila imale ku peeki
(The loss is small, the loss is minimal culmulated in the smallness of the muslim's cap)
8.Eyin to ta yo,wahala enu ni.
( A protruded teeth is a problem to the mouth)
Eyin omo odua, efi tiyin kun......
Olori Orente
Ile la ti nko eso ro ode. Charity begins at home.
ReplyDeleteππππ
Deleteyam pepper scatter scatter, this means isu ata yanyan.
DeleteLabalálá tí ó bá dìgbò lu αΊΉ̀gún, aaαΉ£α» rαΊΉ̀ á fàya.
DeleteAnon you are cray. LMAO. Just can't stop. You are right but funny, how u think am sef?. ROTFL
DeleteIgi ti a feyinti ti ko gba'ni duro, b'owo luni, kΓ² le pani.
DeleteAnonymous 14:10 πππππ
DeleteNaija ninja ππππππ
Anonymous 18:03 ππππ
Anonymous 18:11 πππ
π π π π π π π π π π π π π π π π π π π
ReplyDeleteolori imela. (Olori you have done well.)( @Princess Tever
ReplyDeleteDalu princess Tever
DeleteOlori, I just like your personality and I feel like buying you a gift. Do you use perfumes?
DeleteAwwww
DeleteThanks Anonymous 16:20
Yes I do, God bless you
oro Agba ti o se lowuro,onbo wa se toba dojo ale, meaning the words of an elder that doesn't come to pass now, will definitely come to pass in the future.
ReplyDeleteigberaga loun should waju iparun, meaning pride goeth before a fall.
πππππ
DeleteHahahahha
ReplyDeleteStella mapami ohπππππ
Stella your comment is making me ROTFL, mo n shake head e. But kudos to you. At least you can still speak. Olori go and learn into ooo ki Stella ma shake head e mo oo..
ReplyDeleteHahahahah
DeleteMotigbo oh
Stella which kain intro be this
ReplyDeleteLmao...
Olori thank you for the translation
πππππ
Delete100 gbosa for u olori
ReplyDeleteππππ
Deleteolori Ku ise opolo,
ReplyDeleteAdupe oh
DeleteIgi ganganran maa gun mi loju, okere laatin yee ( A stitch in time saves nine).
ReplyDeleteMeji loore dun moo... (Three is a crowd).
ππππ
DeleteOlori oti she dada ππ»
ReplyDeleteAdupe
DeleteOlor ,olorun a tubo ma fun yi ni agabara ati okun
ReplyDeleteAmin.... Eshey ma
DeleteOwo epo ni araye bani la won kin bani la teje... Abeg olori e so itumo re
ReplyDeletePeople stay with you when things are rosy,they run during difficult timesππππ
DeleteEleyi o make sense Dada
ReplyDeleteMy chocolate, adupe
DeleteOlori eku ise o
ReplyDeleteEshey pupo
DeleteKokoro to n je'fo, ara efo lo wa ati bee bee lo.
ReplyDeleteEmi ko gbo owe daada..
Olori orente atata, e ku ise.
Shey mi o pe de bayi. Nkankan lo n gba akoko mi ni enujo meta yii.
Rara oh, ekabo sori eto
DeleteOloun ayowa πππ
Ijafara lewu, gbogbo ara loogun re....make hay when the sun shine.
ReplyDeleteKoju ma ri'bi gbogbo ara loogun e
DeleteIjara lewu kiise owe!
O mbo, o mbo, awon la nde deee....prevention is better than cure.
ReplyDeleteπππππ
DeleteFalana gbo tiree, tara eni la ngbo.....mind your own business.
ReplyDeleteππππ
DeleteIyawo ti a fijo fe, iran lo ma wolo gbeyin......A party bride will surely taken away by the same course
ReplyDeleteππππ
DeleteBami na omo mi, ko d'enu olomo
ReplyDeleteBeeni oh
DeleteHow do you say no be today yansh face.....?
ReplyDeletebumbum mi ti face back ti pe ti pe..lmao
Eni koni idi ti wa leyin
DeleteHahahhahahaha Stella
DeleteEni koni idi ti wa leyin ππ
TÑa bÑ n bu etù pari òwè yii
ReplyDeleteWhat's the meaning of Ofon tito si gbegiri, ki onikaluku ko eko re lowo
ReplyDeleteEnter your comment...kini itumo owe leshin Oro,Oro leshin owe ni ede geesi
ReplyDeleteProverb is the horse of discussion, discussion is the horse of proverb
DeleteT'ina banji loko majala nio lo sh'ofofo
ReplyDeletePari owe yi eni fun ni ni Fola Toni Adupe
ReplyDeleteKini itumo eni funni ni Fila Toni Adupe
ReplyDelete