Aaaaargh,emo omo oooooh....Emi ni SDK lo oun ko eleyi oh....Arrrrghhhh
1. Ooni ti ilu Ile Ife
2.Olofin ti Ilu Ife 3.Adimula ti ilu Ife
4.Alaafin ti Ilu Oyo
5.Owa Adimula ti Ile Ijesa
6.Osemawe ti Ilu Ondo
7.Ebunwawe ti Ago iwoye
8.Okere ti Ilu Saki
9.Onjo ti Ilu Okeeho
10.Sabiganma ti Iganna
11.Olu ti Ilu Ilaro
12.Akire ti Ilu Ikire
13.Orimolusi ti Ilu Ijebu Igbo. 14.Ayangbunrin ti Ilu Ikorodu
15.Awujale ti Ilu Ijebu
16.Timi ti Ilu Ede
17.Olowo lo ni Owo
18. Owa nbe ni Ilu Idanre
19.Owa ti Igbajo
20.Deji nbe ni Ilu Akure
21.Alake lo ni Egba
22.Ewi ti Ilu Ado Ekiti
23.Olowu nbe ni Ilu Owu
24. Elekole lo ni Ikole
25.Alara ti Ilu Ilara
26.Ajero lo ni Ijero
27.Olubadan ti Ilu Ibadan
28.Soun nbe ni Ilu Ogbomoso
29.Aresa ti Ilu Iresa
30.Ataoja nbe ni Ilu Osogbo
31.Jegun Idepe ti Ilu Okitipupa 32.Odemo ti Ilu Isara
32.Aseyin mbe ni Ilu Iseyin
33.Oluwoo ti Ilu Iwo
34.Elejigbo lo ni Ejigbo
35.Oloko ti Ilu Oko
Kini oruko oye oba ilu yin??
Olori Orente
Auntimi stella eku-ise o, yeye olori orente Eku-ise takun takun, OLUWA aso agbara dotun.
ReplyDeleteAlake ti ilu egba ni emi represent, meanwhile u forgot Oloota of Ota
Egba meji kin jarawon niyan
DeleteOmo ilu mi
Mo gbagbe olota ti ota
Baawa olori!
DeleteAkarigbo of Remo land.
DeleteAlaye of Aiyetoro
DeleteOlupo ti ilu Oluponna
DeleteSoun ti ilu ogbomoso
DeleteWhat about ado ode and ado
DeleteOmo Iwo nimi o
ReplyDeleteIwo olodo oba
Omo ateni gbola
Omo ateni gbore
Iwo oni ilekun
Eruwewe niwonfin dele...
Oruko oba wa ni HRM Oba Abdulrasheed Adewale Ilufemiloye Telu 1( Oluwo of iwoland)
Emi nife si Oba yin..o gbafe daada.
DeleteA ko re ti poju.
Haaaa
DeleteIwo olodo oba
Oba alafe,toh tun kawe
Monife oba yin ooo
Eshe o. Eku ife.. Aaah! Oba wa jasi. oge poju. lol
DeleteMo gbo wipe awon omo Iwo olodo oba ma n rewa l'obirin ati lo'kunrin.
DeleteIwo Omo Ajagun .... Oba nki e lati Oluponna
Delete*winks*
ReplyDeleteπππ
DeleteEku ise opolo ooo......
ReplyDeleteAdupe oh
DeleteOonisa to ilu inisa, in Osun State.
ReplyDeleteOgbayi
DeleteOwa ale ti ilu ikare
DeleteWonderful, but they are not complete I need popo, Eko,sabe
Deletestella tired well good luck
DeleteStella you tried well well. Olori orente weldone, kudos to you.
ReplyDeleteThank you πππ
DeleteJoboyo of inu yara
ReplyDeleteLoooooooolπππ
DeleteYou remind me of an old friend we used to call Arobo sufeπ that guy can die on top woman matter
Deleteπππππ
DeleteHahahahahahahah, arobo sufe. Lol! Lobatan o
DeleteEku ishe oo @Olori orente,omo Yoruba gidi!!
ReplyDeleteAdupe iyalaje tilu ekoππππ
DeleteIsheri
ReplyDeleteOmo oniro ko jefo
Shukushuku eja ni nje
Olu nla
Sagbo dere
Oruka oba ilu mi ni
Alake ilu egba
Omo Yoruba no mi o.....
Omo egba rewa
DeleteAwa omo olumo
Egba agbe wa ooo
Ni*
DeleteAse edumare
DeleteOLOFIN OF ADO-ODO,KITI GBE.
DeleteOlota of ota
DeleteOgbeere
Ti ilu mi ni "Oba Alerinlogba",orisi risi ni ti ilu mi over d decades tori oba ni anfaani lati mu title tii o ba feran,baba mi nje Alerinlogba tori won man kii wa ni ile wa pe " omo amerin wa mo'lu tori baba NLA baba mi mu Erin WO inu ila wa ni ijo na loun!!
ReplyDeleteHmmm
DeleteMonifesi bi oba selemu oruko to wun
Oliri Orente...I love youuuuuu
ReplyDeleteAlakire ti ilu ikire ni temi oooo
Posh hajia, omo Iwo, e Ku ise ooo
πππ
DeleteE she ma. Eku ife. Olohun a durotiwa
DeleteEleko ti ilu Eko - Awa Aromi sa legbe legbe.
ReplyDeleteAwon omo eko
DeleteAromi sa legbe legbe
Omo ilu Cross river ni mi amo omo ilu eko ni oko Mi. Mi ko mo bi won se ma n'ki oba won o.
ReplyDeleteIyawo wa
DeleteEleko ti ilu Eko
Awon omo aromi sa legbe legbe πππ
Iyawo wa. Iyawo rere l'oode oko. Ma worry, a ma ko e bi o se le'ki oriki ilu oko e.
DeleteOlori Orente, e jo wo, e ba was ko aya wa ni oriki eko o.
E je ki n fi eyokan si
ReplyDeleteAlaaye ti ilu Efon Alaaye.
Sugbon, e mi je omo owa, omo ekun, omo....awon temi ni ilu ujesha, e ba mi paari e o.
Mo ma pe yeye baba mi looni lati ki mi ni oriki ilu mi.
E shey pupo.
πππππ
DeleteOriki ma n dun gidi
Haaaa.. ..mo ranti iya babami to ti dologbe
Tan ban kimi, orimi mama wu ni
Olori, kaare o!
ReplyDeleteEku ojo Friday. Eeeh, eduro na, kini ojo Friday ni ede Yoruba?
Eshey oh
DeleteOjo eti ni Friday
Ojo Γ©ti ni ojo Friday n je.
DeleteMonday- ojo aje
DeleteTuesday- ojo isegun
Wednesday- ojoru
Thursday- ojobo
Friday- ojo eti
Saturday- ojo abameta
Sunday- ojo aiku
Ese o, eyin ara le mi.
DeleteOlori orente, eku ise takun takun ooo. omo ilu Epe ni mi ooo. Epe alaro.
ReplyDeleteEshey ooo
DeleteIlu epe....epe alaro ππ
Omo epe ni emi na,epe Alaro ogunmodede,olu epe ni oruko oba wa
DeleteMethuselah eyan iyi..mo ki yin ooo
DeleteE ku ise takuntakun o.
ReplyDeleteOgoga ti ilu Ikere-Ekiti! Ikere oniyan ana
ππππ
DeleteAkarigbo of Remo
ReplyDeleteππππ
DeleteAwujale ti ilu ijebu is my own king. I am omo alagemo merin din logun.
ReplyDeleteIlu ijebu.. ..Eweso ohπππ
Delete@Olori, eku ise o. Oba Alake ti lu Egba re
ReplyDeleteKi ade pe lori, ki bata pe lese
Sugbon o dun mi pe a je ki awon Fulani gba Ilorin lowo wa. O ma se o
Monife ilu ilorin gan
DeleteIlu to jina sina
Toh sunmo aljannah
Ilorin o sumo Oyo, Eko, Abuja, Lokoja ati bee bee lo
DeleteIlorin ilu alfa, enu dun ju iyo lo.
DeleteMo gbe ilu Ilorin fun igba die
Omo Offa ni mi
Olofa mojo
Omo abisu jooruko.
Olofa ti ilu Offa ni ama n pe Oba ilu mi
Olori Adeola, eku ise takun takun
Anonymous 19:09
DeleteEshey pupo πππππ
Olofa ti ilu offa
ReplyDeleteHmm.. ...ilu ofa
DeleteOlofana nipinle kwara
Mrs K awa niyen o
DeleteOlofa mojo, Omo abisu jooruko
Ijakadi looro Offa..
Awa ni omo oni Ijebu egboro, omo a wure fi ase ba enun. Oba ti wa ni Elegboro of Ijebu-Ijesa. Egboro agbe gbogbo.
ReplyDeleteπππ
DeleteEmi ki se omo Yoruba sugbon ilu eko ni won bi mi si. Mio gbo ede ilu mi daada sugbon mogbo Yoruba gan. Ni soki, omo eko aromisa legbe legbe ni mi
ReplyDeleteAwwww.. ...okan ni gbogbo WAππ
DeleteInn ora kete omo Ekiti, oba ilu mi Ni
ReplyDeleteOlukoro of Ikoro Ekiti..emi omo muda sile pariwo end,omo ila orulangun, kere pe Le gi....
πππππ
DeleteIn pele o gbogbo ile,oruko Oba ilu mi ni Owa Ooye ti ilu Okemesi-Ekiti. Oke Agbona a gbe wa o. Ase!
ReplyDeleteNpele ooo
DeleteJegun Oluekun ti ilu IleOluji
ReplyDeleteππππ
DeletePls what of ikare ooooo
DeleteEkushe ooo my yoruba people, I greet you all..
ReplyDeleteAdupe oh
DeleteOmo Ilu Ibara ni Abeokuta lemi o! Oba wa si ni Olubara ti Ilu Ibara.
ReplyDeleteOlori Orente, e ku itesiwaju ede YorΓΉbΓ‘
Eshey oh
DeleteElekole of ikole ekiti
ReplyDeleteOnitapa of itapa ekiti
Obanla of ijesa isu ekiti
ππππ
DeleteOlupo ti Ilu Oluponna ......
ReplyDeleteππππ
DeleteOsogbo oroki
ReplyDeleteEnter your comment...Olojudo ti Ido-Ile
ReplyDeleteSo l
ReplyDeleteALEPATA ti Ilu IGBOHO
ReplyDeleteAjori iwin ti ilu irawo
ReplyDeleteiwo
DeleteEse ooh
ReplyDelete