Stella Dimoko Korkus.com: Oruko Oye Awon Oba Alade Ni ile Yoruba.

Advertisement

Friday, July 13, 2018

Oruko Oye Awon Oba Alade Ni ile Yoruba.

Aaaaargh,emo omo oooooh....Emi ni SDK lo oun ko eleyi oh....Arrrrghhhh



1. Ooni ti ilu Ile Ife 
2.Olofin ti Ilu Ife
3.Adimula ti ilu Ife
4.Alaafin ti Ilu Oyo
5.Owa Adimula ti Ile Ijesa
6.Osemawe ti Ilu Ondo
7.Ebunwawe ti Ago iwoye
8.Okere ti Ilu Saki
9.Onjo ti Ilu Okeeho
10.Sabiganma ti Iganna
11.Olu ti Ilu Ilaro
12.Akire ti Ilu Ikire
13.Orimolusi ti Ilu Ijebu Igbo. 14.Ayangbunrin ti Ilu Ikorodu
15.Awujale ti Ilu Ijebu
16.Timi ti Ilu Ede
17.Olowo lo ni Owo
18. Owa nbe ni Ilu Idanre
19.Owa ti Igbajo
20.Deji nbe ni Ilu Akure
21.Alake lo ni Egba
22.Ewi ti Ilu Ado Ekiti
23.Olowu nbe ni Ilu Owu
24. Elekole lo ni Ikole
25.Alara ti Ilu Ilara
26.Ajero lo ni Ijero
27.Olubadan ti Ilu Ibadan
28.Soun nbe ni Ilu Ogbomoso
29.Aresa ti Ilu Iresa
30.Ataoja nbe ni Ilu Osogbo
31.Jegun Idepe ti Ilu Okitipupa 32.Odemo ti Ilu Isara
32.Aseyin mbe ni Ilu Iseyin
33.Oluwoo ti Ilu Iwo
34.Elejigbo lo ni Ejigbo
35.Oloko ti Ilu Oko


Kini oruko oye oba ilu yin??

Olori Orente

99 comments:

  1. Auntimi stella eku-ise o, yeye olori orente Eku-ise takun takun, OLUWA aso agbara dotun.
    Alake ti ilu egba ni emi represent, meanwhile u forgot Oloota of Ota

    ReplyDelete
  2. Omo Iwo nimi o
    Iwo olodo oba
    Omo ateni gbola
    Omo ateni gbore
    Iwo oni ilekun
    Eruwewe niwonfin dele...
    Oruko oba wa ni HRM Oba Abdulrasheed Adewale Ilufemiloye Telu 1( Oluwo of iwoland)

    ReplyDelete
    Replies
    1. Haaaa
      Iwo olodo oba
      Oba alafe,toh tun kawe
      Monife oba yin ooo

      Delete
    2. Mo gbo wipe awon omo Iwo olodo oba ma n rewa l'obirin ati lo'kunrin.

      Delete
    3. Iwo Omo Ajagun .... Oba nki e lati Oluponna

      Delete
  3. Eku ise opolo ooo......

    ReplyDelete
  4. Replies
    1. Owa ale ti ilu ikare

      Delete
    2. Wonderful, but they are not complete I need popo, Eko,sabe

      Delete
    3. stella tired well good luck

      Delete
  5. Stella you tried well well. Olori orente weldone, kudos to you.

    ReplyDelete
  6. Joboyo of inu yara

    ReplyDelete
    Replies
    1. Looooooool😁😁😁

      Delete
    2. You remind me of an old friend we used to call Arobo sufe😁 that guy can die on top woman matter

      Delete
    3. πŸ˜‚πŸ˜‚πŸ˜‚πŸ˜‚πŸ˜‚

      Delete
    4. Hahahahahahahah, arobo sufe. Lol! Lobatan o

      Delete
  7. Replies
    1. Adupe iyalaje tilu ekoπŸ˜€πŸ˜€πŸ˜€πŸ˜€

      Delete
  8. Isheri
    Omo oniro ko jefo
    Shukushuku eja ni nje
    Olu nla
    Sagbo dere

    Oruka oba ilu mi ni
    Alake ilu egba

    Omo Yoruba no mi o.....

    ReplyDelete
  9. Ti ilu mi ni "Oba Alerinlogba",orisi risi ni ti ilu mi over d decades tori oba ni anfaani lati mu title tii o ba feran,baba mi nje Alerinlogba tori won man kii wa ni ile wa pe " omo amerin wa mo'lu tori baba NLA baba mi mu Erin WO inu ila wa ni ijo na loun!!

    ReplyDelete
    Replies
    1. Hmmm
      Monifesi bi oba selemu oruko to wun

      Delete
  10. Oliri Orente...I love youuuuuu

    Alakire ti ilu ikire ni temi oooo

    Posh hajia, omo Iwo, e Ku ise ooo



    ReplyDelete
  11. Eleko ti ilu Eko - Awa Aromi sa legbe legbe.

    ReplyDelete
  12. Omo ilu Cross river ni mi amo omo ilu eko ni oko Mi. Mi ko mo bi won se ma n'ki oba won o.

    ReplyDelete
    Replies
    1. Iyawo wa
      Eleko ti ilu Eko
      Awon omo aromi sa legbe legbe 😘😘😘

      Delete
    2. Iyawo wa. Iyawo rere l'oode oko. Ma worry, a ma ko e bi o se le'ki oriki ilu oko e.
      Olori Orente, e jo wo, e ba was ko aya wa ni oriki eko o.

      Delete
  13. E je ki n fi eyokan si
    Alaaye ti ilu Efon Alaaye.

    Sugbon, e mi je omo owa, omo ekun, omo....awon temi ni ilu ujesha, e ba mi paari e o.

    Mo ma pe yeye baba mi looni lati ki mi ni oriki ilu mi.

    E shey pupo.

    ReplyDelete
    Replies
    1. πŸ˜‚πŸ˜‚πŸ˜‚πŸ˜‚πŸ˜€
      Oriki ma n dun gidi
      Haaaa.. ..mo ranti iya babami to ti dologbe
      Tan ban kimi, orimi mama wu ni

      Delete
  14. Olori, kaare o!

    Eku ojo Friday. Eeeh, eduro na, kini ojo Friday ni ede Yoruba?

    ReplyDelete
  15. Olori orente, eku ise takun takun ooo. omo ilu Epe ni mi ooo. Epe alaro.

    ReplyDelete
    Replies
    1. Eshey ooo
      Ilu epe....epe alaro 😘😘

      Delete
    2. Omo epe ni emi na,epe Alaro ogunmodede,olu epe ni oruko oba wa

      Delete
    3. Methuselah eyan iyi..mo ki yin ooo

      Delete
  16. E ku ise takuntakun o.
    Ogoga ti ilu Ikere-Ekiti! Ikere oniyan ana

    ReplyDelete
  17. Awujale ti ilu ijebu is my own king. I am omo alagemo merin din logun.

    ReplyDelete
    Replies
    1. Ilu ijebu.. ..Eweso oh😘😘😘

      Delete
  18. @Olori, eku ise o. Oba Alake ti lu Egba re
    Ki ade pe lori, ki bata pe lese
    Sugbon o dun mi pe a je ki awon Fulani gba Ilorin lowo wa. O ma se o

    ReplyDelete
    Replies
    1. Monife ilu ilorin gan
      Ilu to jina sina
      Toh sunmo aljannah

      Delete
    2. Ilorin o sumo Oyo, Eko, Abuja, Lokoja ati bee bee lo

      Delete
    3. Ilorin ilu alfa, enu dun ju iyo lo.
      Mo gbe ilu Ilorin fun igba die
      Omo Offa ni mi
      Olofa mojo
      Omo abisu jooruko.

      Olofa ti ilu Offa ni ama n pe Oba ilu mi
      Olori Adeola, eku ise takun takun

      Delete
    4. Anonymous 19:09
      Eshey pupo πŸ‘πŸ‘πŸ‘πŸ‘πŸ‘

      Delete
  19. Olofa ti ilu offa

    ReplyDelete
    Replies
    1. Hmm.. ...ilu ofa
      Olofana nipinle kwara

      Delete
    2. Mrs K awa niyen o
      Olofa mojo, Omo abisu jooruko
      Ijakadi looro Offa..

      Delete
  20. Awa ni omo oni Ijebu egboro, omo a wure fi ase ba enun. Oba ti wa ni Elegboro of Ijebu-Ijesa. Egboro agbe gbogbo.

    ReplyDelete
  21. Emi ki se omo Yoruba sugbon ilu eko ni won bi mi si. Mio gbo ede ilu mi daada sugbon mogbo Yoruba gan. Ni soki, omo eko aromisa legbe legbe ni mi

    ReplyDelete
    Replies
    1. Awwww.. ...okan ni gbogbo WA😘😘

      Delete
  22. Inn ora kete omo Ekiti, oba ilu mi Ni

    Olukoro of Ikoro Ekiti..emi omo muda sile pariwo end,omo ila orulangun, kere pe Le gi....

    ReplyDelete
    Replies
    1. πŸ™ŒπŸ™ŒπŸ™ŒπŸ™ŒπŸ™Œ

      Delete
  23. In pele o gbogbo ile,oruko Oba ilu mi ni Owa Ooye ti ilu Okemesi-Ekiti. Oke Agbona a gbe wa o. Ase!

    ReplyDelete
  24. Jegun Oluekun ti ilu IleOluji

    ReplyDelete
    Replies
    1. πŸ™ŒπŸ™ŒπŸ™ŒπŸ™Œ

      Delete
    2. Pls what of ikare ooooo

      Delete
  25. Ekushe ooo my yoruba people, I greet you all..

    ReplyDelete
  26. Omo Ilu Ibara ni Abeokuta lemi o! Oba wa si ni Olubara ti Ilu Ibara.
    Olori Orente, e ku itesiwaju ede YorΓΉbΓ‘

    ReplyDelete
  27. Elekole of ikole ekiti
    Onitapa of itapa ekiti
    Obanla of ijesa isu ekiti

    ReplyDelete
  28. Olupo ti Ilu Oluponna ......

    ReplyDelete
  29. Enter your comment...Olojudo ti Ido-Ile

    ReplyDelete
  30. ALEPATA ti Ilu IGBOHO

    ReplyDelete
  31. Ajori iwin ti ilu irawo

    ReplyDelete

Disclaimer: Comments And Opinions On Any Part Of This Website Are Opinions Of The Blog Commenters Or Anonymous Persons And They Do Not Represent The Opinion Of StellaDimokoKorkus.com

Pictures and culled stories posted on this site are given credit and if a story is yours but credited to the wrong source,Please contact Stelladimokokorkus.com and corrections will be made..

If you have a complaint or a story,Please Contact StellaDimokoKorkus.com Via

Sdimokokorkus@gmail.com
Mobile Phone +4915210724141