Stella Dimoko Korkus.com: Itan Ipinle Osun

Advertisement

Advertisement - Mobile In-Article

Wednesday, July 25, 2018

Itan Ipinle Osun

Emi ni Sitella oh......Ejor mo fe beere nkan lowo e..
Se oro yooba ooni fullstop ati comma ni?oro yi,oro Osun state ni!




Osun je ilu kekere kan ni iwo-orun gunsu ile nigeria,osun ti amenu le yii je yo lati inu ilu lakan ti amosi ilu oyo ni odun 1989,oruko ti osun je,jeyo lati ara oruko odo ti oyi ka ti amosi osun jela,odo ti aso nipa re yi tan ka gbogbo ilu osun ti orirun odo na si wa ni osogbo olulu ipinle osun,won ma bo odo yi lodo dun, oje odun kan gbogi ni ilu osun ti gbogbo omo osun ni ti ile toko ati awon are lati oke-okun ni won ma pejo se odun na,ti odun osun si ti di ilu mo ka ni gbogbo agbalaye .


Awon ilu tinbe labe osun ni iwonyi:


1 osogbo (olulu ipinle osun)
2 Ede
3 Ife (orirun ile yoruba)
4 Ikire
5 Ifon
6 ilobu
7 Iwo
8 Modakeke
9 Ilesa
10 Esa-oke
11 Ipetumodu
12 Ire
13 Ikirun
14 inisa
15 Okuku
16 Ode-omu
17 gbogan
18 Iba
19 oba
Ati bebe nlo ni awon ilu na


Kini awon ohun daradara ta tun mo nipa ipinle osun????.


Olori Orente

31 comments:

  1. Omo Iwo nimi nipinle osun.. Loto ilu osun kere amo ani awon nkan toda nibe. Asituni opolopo ile eko to dara nibe. Awon eyan pataki na ti wo je ara awon tiwon gbe ogo naijiria yo na jade nilu osun. Asituni awon tourist attractions nilu osun. Osun oni baje o

    ReplyDelete
  2. Mo gbo wi pe awon omo osun ma n'se daada si omo lakeji won, won de ni iwa. Se ooto ni?

    ReplyDelete
  3. Lols Cynthia and stella be learning yoruba

    ReplyDelete
    Replies
    1. Awon mejeji ngbiyanju gidi ganπŸ‘πŸ‘πŸ‘πŸ‘

      Delete
  4. Omo osogbo oroki lawa o

    ReplyDelete
  5. Ilu eko ni won bi mi si mio mo nkankan nipa Osun sugbon mo mo pe omo Oduduwa ni gbogbo wa

    ReplyDelete
  6. ujesa ni ere, but was brought up in Lagos

    ReplyDelete
  7. I'm from imo state, but my husband is from ilesa, his people are so loving and accommodating, they don't even relate with me as if im not one of dem

    ReplyDelete
    Replies
    1. That's a good thing to hear πŸ‘πŸ‘πŸ‘

      Delete
    2. awa ilesa MO aya WA toju pupo,


      We ilesa can't trade our wife for anything enjoy your stay ojare.

      Delete
    3. Our wife. We the Ijesha people are the best. Ha ha.

      Delete
    4. Yinmu best indeed

      Delete
  8. Erin osun da?
    Iya mi omo erin osun ni o

    ReplyDelete
  9. Gbogbo awa omo Yoruba
    Ti topic kan bawa te fe kin muwa, ejowo eje kin MO
    Monife gbogbo yin

    ReplyDelete
    Replies
    1. E ku'ise. A ni'fe eyin naan.
      Awon akori ti e le soro le lo'ri ni awon asa aye atijo. Eg, asa igbeyawo ati ojuse alaarina, culture of women kneeling for their husbands till they finish eating, ila kiko, asa isomoloruko pelu awon eronja ti a ma n lo ni ile Yoruba, itan Oduduwa ati adiye onika mefa ti o seda Ile-Ife ati bee bee lo.

      Delete
    2. Motigbo, ma sise lori eπŸ‘πŸ‘πŸ‘

      Delete
  10. Olori orente eku ise takun takun, awon omo nko o, omo ilesa nimi o, mio tide ile ri, sugbon laipe laijina malo silu babami,

    Anife eyin naa o.

    ReplyDelete
  11. Ni Odun 1991 ni a da ipinle Osun sile lati inu ipinle oyo

    ReplyDelete
  12. Ilu osun ni mo sin Ile Baba...

    Ni ilu gbongan gangan...
    Ile aye rorun, faaji sise o Na mi lowo pupo.

    Ti ilu gbongan ba ti su mi, mo ma lo si ilu Ibadan lati lo se faaji nitori ko jina.

    Ni igba ti o to lati se eto idibo ti gomina, won gbe mi lo orile-owu lati pin cardi idibo, awon kokoro to je mi ni ilu yen o se fi enu so.

    A! Mo fe le sunkun. Mo ya lo bebe lowo oga wa ki o ma gbe mi kuro ni gbongan fun idibo gangan.

    Nkan o won ni Osun, ounje ni o, Ile gbigbe ni o, owo irinse ni o.

    Mo ma n mu emu ni ibi abawole si gbongan yen, ma ra eran igbe lowo iya to ma n ta iyan nibe.

    Faaji agunbaniro...

    Mo ti pada lo ilu yen ni eemeji leyin ti mo pari sisin ilu mi.
    Awon Omo kekeke ti won ma n wa sodo mi si ti dagba..

    Gomina won o kan gbadun ni.

    Ilu Osun, Ipinle Omoluabi

    ReplyDelete
    Replies
    1. πŸ‘πŸ‘πŸ‘πŸ‘πŸ‘

      Delete
    2. olori orente, ejowo ebawo so fun awon omo ilesa ti won wa Nile wipe IYAWO kii Se eru.

      Delete

Disclaimer: Comments And Opinions On Any Part Of This Website Are Opinions Of The Blog Commenters Or Anonymous Persons And They Do Not Represent The Opinion Of StellaDimokoKorkus.com

Pictures and culled stories posted on this site are given credit and if a story is yours but credited to the wrong source,Please contact Stelladimokokorkus.com and corrections will be made..

If you have a complaint or a story,Please Contact StellaDimokoKorkus.com Via

Sdimokokorkus@gmail.com
Mobile Phone +4915210724141