Ounje Yoruba ma dun gidigan
IKOKORE |
LAFUN JE OUNJE TO WOPO JU LAARIN AWON ARA EGBA .ONJE OKELE NI LAFUN JE AROMORA SII NI PELU.A LE FI ORISIRISI OBE JE SUGBON OBE TI O TAYO JULO PELU RE NI OBE GBURE OLOBORO ATI ERAN TABI EJA A SI LE FII GBONMO GBE SOFUN.
2.IYAN:
awon Yoruba a maa so wipe iyan to wewu egusi,to de fila isapa….I-Y-A-N. a baa lowo awon baba nla wa o si je ounje to gbayi julo nile Yoruba.isu lama gun felefele ninu odo titi yo fi di iyan a le fi isapa je tabi obe egusi sugbon obe to tayo julo ni obe efo elegusi tabi riro ki a wa fi eran igbe de lade. a le fi emu ogidi sin losale.
3.SAPALA:
sapala elepo he okan lara ounje Yoruba ,o jo moin-moin pupo sugbon agbado pelu ata ati epo pupa ni a fii ma n se sapala.awon elomiran a maa je lasan awon miiran a si ma mu gaari olomi tutu peli re.
4.IKOKORE:
Ikokore je ounje to gbajumo laarin awon ara ijebu.isu ewura ,ata,epo ati awon eronja bii ede,eja la ma fin n se ikokore yii a si le je pelu eba tabi okele tomba wun nii.
5.EBIRIPO:
Ebiripo je onje to se koko fun awon ara ijebu.isu koko ni a ma fi n se ebiripo a sii pon sinu ewe sori ina bii eni pon moin-moin.obe eyikeyi to ba wuni nii na fi n tii sonafun.
6.ASARO:
Asaro elepo je ounje to gbayii laarin gbogbo omo ile kaaro-o-jiire.Ako isu pelu epo pupa ati ata,eja ni a maa fi n se Asaro .aropo sii lama fii se ni ori ina.a le fi omi tutu tabi oti olomi osan tee lo si ona ofun.
7.EGBO:
Egbo je okan lara ounje ile Yoruba.Agbado funfunni a o se lasero petepete.a le je pelu ata dindin tabi ki a fi ororo yii pelu ewa aganyin.
8.OFADA:
Ofada je iresi ile Yoruba ti o sii maa n muni
datami.ile Yoruba nii a ti n gbin a sii ma se bii eni se iresi gangan.Ata dindin to ta lenu sue-sue pelu awon eronja bii igbin,eja gbigbe pelu eran tabi ponmo dee lade.
Ewo Lani ife si julo ninu won??
Olori Orente
Olobe lo loko leleyi o olori orente.
ReplyDeleteI love asaro elepo. The taste is divine.
DeleteWeldone olori Orente
Sokoyokoto😀😀😀
DeleteIyan ati efo worowo pelu opolopo ede pupa, eja gbigbe, eran lorisirisi ati iru wooro a maa ladun pupo
DeleteOlori Orente, emi a maa je Jogi, Mosa, ojojo, Egbo, adalu ewa, efo elemi meje, obe dudu, Eko ati bee bee lo
DeleteI don't like ikokore but ofada is bae anytime any day
DeleteI love love love ikókóré and èbìrìpò,our favourite food from my precious state,i'm a great jebusite/Fulani,mixed tribe.What is Lafun and Sapala?I couldn't read the write up very well cos there is no àmì on it but nice write up though.
DeleteAnonymous Bug
Check out ikokore_ on instagram and thank me later
DeleteSomeone should please read and translate.
ReplyDeleteShe's telling us about different foods the Yorubas in different state love to eat like Amala, Pounded yam, Ofada rice, Pottage, Porridge etc.
DeleteWednesday, June 20, 2018
DeleteOrishirishi Ounje Nile Yoruba
"The Yoruba bread is sweet
FREE
1.HIP:
I LOVE YOU TO REMEMBER THE OTHER MEMBERSHIP OTHERS THAT I HAVE BENEFITED WITH THIS MEMBERSHIP. WHEREAS THE RESPONSIBILITIES OF THE MEMBERSHIP REQUIRED THAT THE JUDGMENT OF THE JOURNAL ORIGIN OF ORIGINAL OR WARRANTIES OR REQUIRED HOW TO READ MORE.
MODERN:
Yoruba people say that the famine is a dangerous cat, and it's about to escape. ... Yes. We get from our ancestors and it is the cheapest food in Yoruba. The lush tortoise in the river until it becomes dry can be scorched or fried egg but the sweetest sauce in the pebbles or crows comes add lacquer meat. This is what the Bible says.
3.SAPH:
Pumpkin is one of the most common food in Yoruba, it is very fun but garlic with red pepper and red is being used as a non-other. .
4.Young:
Unconcerned foods are a popular food among different kinds of hazards, peppers, oils and societies, as well as fish, and this fish can not be cooked or eaten by the rabbit.
5.EBIBRIP:
Grooming is a very important diet for the body of the body. It is usually used as a replacement and is embroidered in the greenhouse on the fire as a focal point. Anything that is so appealing is very encouraging.
FIRST: Cultivation
is a common ingredient among all indigenous people. In coconut with red oil and pepper, fish are usually cultivated. It is more common in the flames. We can water cold or orange juice go to her own.
7.Express:
Eating is one of the Yoruba foods. The white potato is well-researched. It can be cooked with pepper or sprayed with oil.
8.With:
Of course, it is a
poisonous poison in the Yoruba population. It is Yoruba that we are cultivating it and it does not matter exactly what it's like. It's a long way to try it with some tips like snails, fish with meat or soup. write lade.
Whose love is the greatest love in them?
Prince of Orente"
That's the translation according to my phone😅😅😅
Hahahaha
DeleteKidjo o ti gba penalty lo throwing 😀😀😀
Na real translation
DeletePoisonous Poison bawo kidjo?
DeleteJowo mura si ise Mamalawo ti o moo se. Ma fun wa ni majele je.
Olori Orente, ku ise takun takun.
Ageless T, LMAO. Na real mamalawo.
Delete😅😅😅😅😅
DeleteAgeless T, don't mind my mischievous phone o jare🙈🙈🙈
For some minutes i was applauding you, when you now said your phone translated it
Delete😂😂😂😂😂😂😂
Pepper just entered my eyes as I opened this post.
ReplyDelete*screams for water*
😂😂😂
Delete💧 💧 💧 💧 💧 💧 💧 💧 💧
DeleteE WO labosi...ta ba ri ohun to da ka wi
DeleteYou've gone bonkers 😂😂😂😂😂
DeleteHahaha
DeleteBlackberry Pele... .ata yen po😀😀😀😀
O npe!
DeleteOk I have tasted all the foodie very sweeties..
ReplyDeleteKini aje okuta ma mu omi yi mo?
DeleteIyan ati Ofada nikan ni mo nife si ninu gbogbo won. Mo k'orira Ikokore ju igbe lo. Koda Asaro, Ebiripo ati Ikokore maa n dabi igbe loju mi iyanma
ReplyDeleteI changed to English so I can get the meaning and it translate ofada as WITH no7 as express and others with I don't understand .does it mean Yoruba no get English meaning
DeleteLMAO People don't read this in google translation. I died laughing hahhahaha
ReplyDeleteMo nife iresi ofada gidi gan mo si ni die nile pelu, mo ma n dinta si pelu opolopo epo pupa ati iru woro. Olori Orente o gbiyanju gidi pelu akosile orisirisi ounje yi... O dami loju wipe oko re yoo ma je orisi ounje aladun nile. Egba meji kii jara won niyan, Egba lemi naa ti wa.
ReplyDeleteBa wa
DeleteNice one Olori Orente. Eyi ti mo nife si julo ni Ofada ati Iyan. E she pupo.
ReplyDeleteYepa! Come see me salivating here
ReplyDeleteOunje aladun
ReplyDeleteEmi nife si Iyan ati obe egusi gege bi omo Ijesha rere ti mo je. A ma n jiyan ni owuro, osan ati ale.
ReplyDeleteLeyin Iyan ni lafun. O je okele ti o yara la ti se. Obe gbegiri ati ewedu ni mo fi n ma je lafun.
E ku'se takuntakun iyaafin Olori.
Ehn ehn...sepe omo ilu iya mi ni prudent.
DeleteOmo ijesha ti o ridi isana, ile ni omo owa ti n muna roko.
Iyan ati egusi tabi efo riro ko LA fi we
Ara ile tiwa oja
DeleteEkasan eyin temi
Beeni o Elegant. Ijesha ni me e re. Ori mi a ma wu pupo ti mo ba gbo oriki Ilu mi. E seun gan lopolopo
DeleteOlori Orente..e ku ise ma. e mi o nife lafun oo.
ReplyDeleteelubo isu ni no nife si. Iyan ati efo riro, iresi ofada ati at a dindin elemi meje 😜
ki lo n je sapala??
e ku ise oooo
Emi o like ikokore tele tele, but moti bere like e die die😁😁
ReplyDeleteMo like isu gan, so asaro dun mi gan gan. Mo like pelu iyan sugbon the big belle no be here😅😅😅😅
Emi o like ofada tele but mo je ni Keresimesi to koja pelu ayamase! Chaiiiiii😋😋😋😋 I must be multilingual by force. At all at all na im bad pass😂😂😂
I hail all my naija people on. Every tribe matters👍👍👍👍
Ogbiyanju
DeleteErm...this one pass me o🤔 #head-scratching emoji
DeleteHahahahaha.....I am saying you tried 😀😀
DeleteAh..okay. Thanks 😅
DeleteMsheww
ReplyDeleteA tun le pe sapala ni abari
ReplyDeleteI love yoruba foods...the more pepperish the better 😆 and I make the best ikokore ever 😋
ReplyDeleteAbi omo ijebu ruwo wa?
Delete@Ageless I'm not yoruba.
DeleteMonifesi Iresi Ofada . lopolopo igba ni mon manse fun oko mi. Omo egba ni oun nan de nifesi
ReplyDeletekare olori orente, ani opolopo ounje aladun ni ike Yoruba, lara won no abari,to w/o nd I agbada ,expo,ait ata se,ojojo, isu gbigbo no won fi n din,ekuru naa o gbwyin
ReplyDeletea dara fun o,olori
Amin o
DeleteOlori Orente e Ku use jare..
ReplyDeleteHa! E mi mu ranti egbo, igba to mo wa in ile iwe mefa ni mo ti he gbeyin mi o de mo n se.
Mo ni fe ofada gidigan ati asaro( ka sa sope gbogbo ounje to a le fi isu se).
Mo feran iyan gidigan, oko mi na si feran re, ti mo ba fe ko she nkan funmi tabi ti no fe wu Lori ni mo ma n guyan.
Olori booya ti e ba Raye ki e she eto Lori obe orisiirisii.
Iyawo rere lode oko
DeleteMA gbinyanju
BlackBerry ata ko se ni kosi oju 're,toju bole eran iya Nuru,nigbati kiise roo oko ati obo ni a n so,mi o mon nkan ti o wa debi
ReplyDelete
ReplyDeleteIn ma gbage-e o Ijesha, Omo Owa o Ijesha, Omo Eleni ate iika, Omo Eleni Ewele.
In pele o gbogbo eyin Ijesha, Omo Ogedengbe, agbogun gboro, adi pon pon l'oju ogun,
Npele o gbogbo Omo Ujesha, N'ile, L'oko, L'ona Oja, Emi Omo Owa ni Mo mi kin iin o, Aa kere Oko d'ele o!!!
Upele olujesha
DeleteAnon 13:11, o se pupo.
DeleteE Ku use takuntakun.
ReplyDeleteAkiyesi mi no one ebiripo, kii SE ounje Ijebu, Remo lo Ni ebiripo.
Koda, ara Ijebu miiran ko no Ogun to a n PE Ni ebiripo.
Lafun Ni mo korira ju, oorun re Ni mo korira ju, Lati kekere.
A dupe fn Olorun to o fun way Ni aeon ounje mere-mere yii Ni ile yooba.
Ma kiyesi iyen
DeleteMa kiyesi iyen
DeleteMi o je sapala ri o
ReplyDeleteEkasan omomi, omodada Olori orente, esegon for this😅😅😅
ReplyDeleteIya oo🙌🙌🙌🙌
DeleteEshey ooo
Mo je ikokore. Mo love eh kpa kpa
ReplyDeleteHahahhaha.... Lobatan
Delete😂😂😂😂😂
DeleteDespite the fact pe Omo Igbo ni mi, ni igba ti mo loyun, amala ati ewedu ni ounje ti ko je kin throw up. Mi kin fi ounje yen sere rara. Ata yen gan gan ni koko...
ReplyDeleteBeni oh, ata yen ni koko
Deletegbayi jare. 👊.
DeleteOlori Orente, e jowo e se alaye fun wa, bi a se nse obe isapa ati sapala. E seun
ReplyDeleteOlori e ma ku ise oh...
ReplyDeleteMo nife ofada iresi ati Asaro elepo pelu ogunfe... 😁
Awon Ounje Yoruba ma dun gaan sugbon ata maa poju...
ata yen gan ladun ibe.
Deleteo ti mu mi ranti ogufe o. sugbon Moti ra eran pupoju pamo sinu freezer. O nwu mi je gan bayi
Olori orente, kuu'se. Mon feran iyan pelu obe efo riro. Ti a ba fi epo pupa se efo riro, ti a we ata si tia ko je ki ata ko kuna, ki a wa ya eran igbe si, pelu igbin ati ede, pelu eja gbigbe. Oluwa o... ki iru woro o maa sere ninu re, yepa! Ki eyan fi eleyi je iyan to kun'na daradara. Chai! Yoruba dun.
ReplyDeleteOmo yòòbá ponbele ni è. Mo ni fesí akajuwe rè👍👍
DeleteHa ori e pe gan ni. Ki eyan ri iru iyan ti o juwe yi je. Aye re a ma dara o. Mo nife si egbo na, amo mi o ri ra ni ilu eko yi. Egbo pelu ewa aganyin ati ata dindin ti o kun fun orisirisi tinu eran o ma'am dara gan o
DeleteMo ni ife asaro elepo kpukpo...ati atarodo.
ReplyDeleteolori orente, mo gba fun e. eku ise opolo. iyan ati obe isapa ni mo feran julo, sugbon oseni laanu pe isapa ko seri ra bitigba kan mo.
ReplyDeleteIyan ati efo elegusi, ofada ati asaro elepo rede rede ni moni Fe siju Ninu gbogbo ounje yi.ku ise opolo olori orente
ReplyDeleteOfada ni o se ohun gbo gbo 😂😂
ReplyDeleteObe Ofada pelu eran orisirisi ni a je ju ni ilu Germany. Okan dun mi ni pe epo Togo ni won tan nibi. Awon oniyeye ko ni je ki a gbe epo wo inu oko ofururufu. Oma se o
Olori Orente ishe le'she sugbon ko si ewa ati agbado nibe....hahahaha
ReplyDeleteOlori asaro elepo rederede pelu eja tutu ninu re ni mo feran
ReplyDeleteI love it
ReplyDeleteI love it
ReplyDeleteI love it
ReplyDeleteBa wo ni Won se se
ReplyDelete