Stella Dimoko Korkus.com: IWA OMOLUABI NILE YOOBA

Advertisement

Advertisement - Mobile In-Article

Friday, June 15, 2018

IWA OMOLUABI NILE YOOBA

Awon da?Mo ni awon daaaaaaaa?Mon se intro post yi...emi ni SDK oh...

Eese me lo ko gbo gbo post yi oh...heheheheheheh sho get?




Iwa jẹ iṣesi eniyan kan laarin awọn olubagbe rẹ. Bi iṣesi ẹni ba dara, awọn eniyan yoo maa pe oluwarẹ ni oniwa rere. Bi iṣesi oluwarẹ ko ba si bojumu, awọn eniyan yoo maa pe e ni oniwa buburu. Awọn ti iwa wọn ba dara ni Yooba npe ni ọmọluwabi eniyan.


Ohun ti Yooba gba pe o jẹ iwa ọmọluwabi pọ pupọ.


1.O bẹrẹ lati ori kikini ti o fi de ori aajo eniyan ṣiṣe. Eyi ti a le sọ pe o jẹ ipilẹṣẹ iwa ọmọluwabi ni ikini. Yooba gba pe ẹni ti ko ba mọ eniyan ki ko yatọ si ilabiru baba ọbọ.


2. ibọwọ fun agba tun jẹ ọkan gbogi. Bi eniyan ba fi ọjọ kan ju ẹlomiran lọ, ọwọ(respect) ọjọ kan naa yoo wa lara rẹ titi dọjọ ogbo wọn ni. Bi Yooba ba si sọ pe papanlagi tabi ipanle ni ẹnikan, aini ibọwọ fun agba pẹlu ohun ti awọn n tọka si lara rẹ.

Eje ka jiroro awon iwa ti agbodo mawu gege bii omoluwabi.

Olori Orente

51 comments:





  1. OUR OBJECTIVE OVERVIEW
    Do not hesitate, I'm not sure what I'm doing ... I'm intro post ... I'm SDK oh ...

    You just did not hear this post oh oh ... heheheheheheh sho get?





    Violence is a person's mood among your peers. If a person's attitude is good, people will call him a good person. If the mood does not fit, people will call you a bad person. The quality of their behavior in Yooba is called humanity.


    What Yooba acknowledges is that he is a very modest person.


    1. It starts from the head of the head that leads to a busy human race. This can be said to be the origin of behavioral behavior in the first place. Yooba believes that the person who does not know man is not different from that of the father.


    2. The glove for the club is also the same. If one person passes one day more than another, the respect (respect) the same day will come upon him until they are old enough. If Yooba does not say that the globe or the secular is someone, the need for gloves with what it means applies to you.

    Let's talk about behavioral behaviors that are just as unfair.

    Prince of Orente


    See wetin google translste for me... Hehehe

    ReplyDelete
    Replies
    1. My sister onye amibo! Hehehe... What are you doing here?😂

      Delete
    2. I am "vassatta" in sweetie's voice 😀😁😁

      Delete
    3. In chief zebrudaya's voice Google translation is " fa fa foul"

      Delete
    4. Hand if I esitate nko?

      Delete
    5. @Amanda,not correct at all

      Delete
    6. @Amanda... Google Translator is wrong

      Delete
    7. Anama wonder, Amanda ogini ne Meh here?

      Delete
  2. You people like competition ahh! Igbo language is still much outstanding. Ndi ofe nmanu

    ReplyDelete
    Replies
    1. Ya n mmiri...

      Delete
    2. Omo ajokuta ma momi,a fipa ji baba lori eni

      Delete
    3. MMM ti ji owo ati opolo e, kini buruku alainironu.

      Delete
  3. ododo oro.mo ki gbogbo eyin omo ijebu alare.ki ojo oni San wa sowo,somo ati si alaafia.Stella ori e wanbe.o lenu.

    ReplyDelete
  4. Mgbati mgbati mgbati! Mgbaaaaatiiiii


    Ndi mgbati ngwanu bia nu eba

    ReplyDelete
  5. Nice one!!! Interpreters where una dey?

    ReplyDelete
  6. Olori ekuse tanku tanku olorun asogbara dotun..
    Moka iwe kan nigbati mowa secondary school akole iwena ni iwe lewa omoluabi..
    Mofi akokoyi nbegbogbo awa alejo SDK wipe ki aima bowo funrawa nipa orosiso. Aimoroso ati kama buyan tile opolopo eiyan kuro Lori bloggi yi.. Aije tun da kaima ponrawale laijo eiyan. Eyini moriso. Tobaju enu Milo ejo eyin agba edarijimi..sebi emope omode kimo eko nje komara lowo..
    Otundigba ooooo...

    ReplyDelete
    Replies
    1. If them dare remove "gb", this language will cease to exist.

      Delete
    2. Eshey oo
      Iwa omoluabi nika ma fi ba gbogbo eyan lo

      Delete
    3. and if "kp" is removed from ibo it wont exist either

      Delete
  7. @Olori biko bia kowaram ihe edere na ebea , na muwa aghotaghi ya ma oli

    ReplyDelete
    Replies
    1. Kini nkan ton so
      Koyemi

      Delete
    2. Ìwà tó ti sonù ló jé kí gbogbo ayé dojúrú. Tèmbèlèkun, òtè àti ìwà anìkànjopón ti bayé jé

      Delete
    3. Kini katikati ti Tever n so?

      Delete
  8. I want to learn o, who will teach me free?

    ReplyDelete
  9. This comment has been removed by the author.

    ReplyDelete
  10. Omoluabi ni Stella naa. O se Pataki kii gbogbo ma wuwa to DA si enikeji wa nitori pe a mo ibi ti a mati pace on I iranlowo wa.

    Its been long I wrote in Yoruba.

    In a nutshell, Stella was saying: 1. We should be of good behavior and secondly always be full of respect to our elders

    ReplyDelete
  11. I I av finished reading hall of hit.
    The thing made halot of sense.
    I ope you will post hanother one
    appy friday to hall of you!

    ReplyDelete
    Replies
    1. Hi like your haccent. It his very beautiful. Hi am sure you are Hans gan

      Delete
    2. I meant 13.25.

      Delete
    3. @ 13.25 and 14.50, my neighbour just kem in through my get with some brade. She tried to make me test some,but l reifused because l just had some cakes which were made with too much floor(flour?). She said she would folo me inside because she hated'people that doesn't reverence their nebors' Love you too.

      Delete
    4. 😂🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣 u people are mad oh...
      Feyifunmi 😂😂😂😂😂😂😂u are mad

      Delete
  12. Omooluabi gidi ni olori orente...

    ReplyDelete
  13. Beeni Iwa lewa omo eniyan,odara lati MA wuwa bi omoluabi pelu ara ita ati awon alaba gbewa,iteriba fun Agba si Se pataki, ki olorun MA ti wa leyin lati wu iwa rere. Ku ise takun takun olori orente.

    ReplyDelete
  14. Iwa omoluabi ni ki a gba eru lowo awon to ba ju wa lo.


    Ki a dide Lori aga fun agbalagba

    ReplyDelete
    Replies
    1. Oye ki gbogbo wa do omoluabi

      Delete
  15. olori ku ise opolo, awon were omo atohunrinwa ibo to own n so isokuso,nigbati won she tiwon a o lo ibe lo ma ko ikokuko o,but ase ti wa ara n ta won,inferiority complex, always feeling inferior, awon omo Iran kiran gbogbo

    ReplyDelete
  16. E seun Olori Orente. Eku gbo gbo e.
    SDK, mo get e baje 😁

    O je ki a ma wuwa rere. Ko je ko je pe nitori esin wa. Sugbon ki o je nitori pe o se pataki ninu gbo igbese wa. Ibukun ni fun eyin ara

    ReplyDelete
  17. Olori Orente.. Ku ise takun takun 😁. O da ki a ni iwa rere.

    ReplyDelete
  18. O se o iyaafin olori Orente. O dara ki eniyan je omoluabi. Iwa le'wa, iwa a ma n gbe eni de ibi giga. Iwa rere a si ma silekun ibukun. Aimoye awon ti o ti so ifa ati ebun danu ni ori blogi Sdk nitori iwa ai bojumu. E je ki gbogbo wa tun iwa owo wa se, ki a tun fi iwa owo wa tun orileede wa se. Mo ki yin o gbogbo omo oodua.

    ReplyDelete
  19. Eku ise iya gbogbo (Stella). Olori Orente mo ki yin naa. Adura mi leni nipe Olorun a ma bukun wa ni ona ti o ma ya wa lenu. Ninu alaafia ni a ma wa ni gbogbo igba, ni oruko Jesu, Amin.

    Amanda or whatever you call yourself, please remove your comment. The interpretation you gave is very wrong. Do not make a mockery of Olori Orente's write up. And to your fellow intolerant tribe, pls be respectful of other people'say culture. If you have nothing positive to say/write please move to other posts or better still move to the Igbo post of yesterday and knock yourself out.

    ReplyDelete

Disclaimer: Comments And Opinions On Any Part Of This Website Are Opinions Of The Blog Commenters Or Anonymous Persons And They Do Not Represent The Opinion Of StellaDimokoKorkus.com

Pictures and culled stories posted on this site are given credit and if a story is yours but credited to the wrong source,Please contact Stelladimokokorkus.com and corrections will be made..

If you have a complaint or a story,Please Contact StellaDimokoKorkus.com Via

Sdimokokorkus@gmail.com
Mobile Phone +4915210724141