Mo ki gbogbo omo oduduwa ni ibigbogbo agbaiye. Mo ki gbogbo ololufe sdk.
Mo wa ki Stella funrarare fun akitiyan re lori blog yi. Mo ki gbogbo Angeli oluranlowo to wa lori blog yi, Oluwa yoo ma a gbe owo yin soke (amin).
E je ki a gbe asa ati ede wa laruge lori blog yi gbogbo eyin omo Oduduwa ni Nigeria, Cuba, Brazil, America, London ati ni gbogbo agbaiye.
Emi ni Abeke, isheri omo oloko, omo olu nla, omo tana o to je su aya won ni ilare, Ile Ife.
*Abeke Ese pupo.mo busy gan tabi ma ba eyan mi chat ni...kikikikikikiki
Noted, please I need a translator on this.
ReplyDeleteJust passing..... Iranu
DeleteKi le leyi so??
DeleteKo easy rara ooo..kikikikiki
@MARTINS ABOY
I'm not omo Oduduwa. I'm an Ilaje guy. My forefathers were/are the owners of the Great Ife city. We are the progenitor of the Yoruba race, not Oduduwa
DeleteFuck shitt! Pls translate "Nigeria" in your language.
DeleteYoruba:
Ibo:
Hausa
Edo
Isoko
Urhobo
Calabar
Esah
Itsekiri
Akoko Edo.
In Patt Ogar's voice leave your name, account number, bank name under your answer, I will deposit the equivalent of $50.00 into your account. I'm doing this for my birthday coming next month.
##Sagittarius.
Akiyin gbogbo omo yoruba SDK.. Dada lamo bara wa se o... Amin.
DeleteMo ki gbogbo omo kaaro o'jire to wa ni bulogu yi, se alafia ni awa? Anu ati ojurere olorun o ni fi wa sile o. Abo re o ma wa pelu wa lai ati titi lai Amin🙏💋
DeleteEkaro ooo omo mi. Se owa kpa. Ekushe ooo
ReplyDeleteEwa joko...
DeleteEwa joko...
DeleteMo fe dobo mabinu, lol.
ReplyDeleteClown!!!
DeleteHahahahahahha 😂😂😂😂😂😂
DeleteO mo ju obo lo ni? Onise kuse, onido ku do,LOL
DeleteOfe dobo? I hope u understand wetin u write so?
Delete**Order your boxers, Singlets, socks, @ affordable rates. We deliver **
Obo aja abi ti malu?
DeleteLol weirdos
DeleteBlackberry please leave me alone.😃
Delete@shakiti baby no kill me with laugh 😂😂😂 obo malu
DeleteLmao
Delete
DeletePlease translate smelly pussy in Yoruba and Ibo language.
Kikikikikikikikikikikiki, the struggle to stay relevant is real...hehehehehehehehehe
ReplyDeleteEku gbadu o, ma yoruba brethren.
Bia, who is struggling to stay relevant. Tribalistic, educated illiterate.
DeletePipi Lee why?
DeleteLmaoooo...uneducated literate, I actually struggled to stay relevant by writing something no matter how small in your language.
Delete#ByeAnonymousTribalRat
Aja lo ma a je enu iwo omo kpikpi Lii yi. Ta l'egbe iya la ya e nibi? Pare bi iso...
DeleteAja lo ma a je enu iwo omo kpikpi Lii yi. Ta l'egbe iya la ya e nibi? Pare bi iso... @Lara Pererenpe
DeletePipiliyi onoranu, nsoro aja njo. Omo ale jatijati!
DeleteRelevant on an unknown blog you mean Kai lack of sense
DeleteAnon 18:47&20:02... onoranu, nsoro aja njo. Omo ale jatijati!
DeleteEmi na ki e Abeke. Olorun ma ke e. Omo calabar ni mi o sugbon mo gbo ede yoruba daada.
ReplyDelete*mo fe wa laye ti ti ayeraye*
Kare jare!
Deleteinn okun o sisita sitella,se alaa ni?
ReplyDeleteHaha.. Anti mi Leo, shey omo okun niyin ni?
DeleteSe Ekiti loore ni abi Ijesha?
DeleteEkiti niyen ke,a mora wa taaba ri ara wa#kikikiki
DeleteAala funfun gbo ooo.
DeleteOmo Ekiti ni me ha.
Okun awe...
Maa ju'yan re lo luka luka
Lara alabajo ti mo maa'n gbadun e, asé omo Ekiti ni é.. 👍👍
DeleteIñ orà oo kete ulé... Sé ala loi a?
Kete rà lao keré oko dele o lasé loí Eledumaré.
Oní a sañ a ooo...
DeleteAala ni o.
DeleteIyan a yun lenu re awe!
Karé lu a mí.. Anon 18.51
DeleteAra ule mo waja..e okun OK kete omo ekiti
DeleteOni a dara o Stella.
ReplyDeleteAbeke was gbayi!! Omo oduduwa to splufic..
ReplyDelete*wa
DeleteO sha mo!
DeleteKilode ti e fi ami faweli si yoruba ti e n ko.
ReplyDeleteIbeere.
DeleteLol!
Mo n sere ni o
Ki'n to gbagbe. Shey Blog o ni nkan ti'n won pe ni ede yoruba ni? Awon omo ibo ma wa sibe wa shey wahala sugbon KOLE WERK.
ReplyDeleteAbi...
DeleteNiklaus, omo 'yibo' la n pe.
Bulogi ni a mo si ni silebu Yoruba.
DeleteStella has got ingenuity and this makes the blog unputdownable.
ReplyDeleteI don't know kpikim in Yoruba. I slayed my Igbo joyfully the other day, so Yoruba speakers carry go
Same ere dear, they got u today lol after we flexed our igbo for them.
DeleteYes oooo,you did well,Eka Joy we need your attention here,come and do the needful.
DeleteMi o fe ran yi lowo loni, ki won to wa pe mi ni sabinus. Mi o le wa pa ra mi
DeleteEka joy karin kapo, yiye lo n'yeni. O le mumi a, ko jata a lofe o. Ajemonu lawon arami lokunrin ma fi o se gbeyin.
DeleteEma binu o, odabo. Kikiki.
ReplyDeletePhewww
ReplyDeleteCopycats bc someone posted in igbo.
DeleteAbeke,oshe pupo,olorun awaa pelu Iwo ati awon ara ile re gbogbo. Abileko 'Sitela',oku use takun takun,emi n gbadun gbogbo a won nkan ti mo n rii Lori bulogi re yii o. *wipes sweat*
ReplyDeleteStella kin she abileko o, iyaafin ni. Ile oko lo wa fa
DeleteYou are right and am wrong. Just checked up
DeleteObirin to wa ninu ile oko ni yoruba npe ni Abileko. Abileko ni Sisi Stella o.
DeleteEyin temi kilon sele?
ReplyDeleteSe gbogbo e nlo?
Mo fe sare de salon
Ma ri yin to ba ya.
Ose, padi mi Chi to wa exotic.
DeleteMo n feel e gan
Je knuckle
Ori e wa nbe Jo. Igbe e onile, o mama to ni.
DeleteMofi asiko yi dupe lowo Abeke fun akitiyan ati gbe ede wa laruge. Motun fi asiko yi dupe lowo SDK omo araye onibayo e je ooo. Amin.
ReplyDeletejust passing .......
ReplyDeleteHmmm
ReplyDeleteNi Ohun kiss Daniel " Stella ngbo o dat am sorry as I read your yoruba Erin ni mo Rin*
ReplyDeleteNa so e be now? Make me self go compose isoko blog post come send to stella. Isoko wadooo! Isoko wadooo! Wa dhe?
ReplyDeletewho wrote this
ReplyDeleteI thought Stella don't know how to speak yoruba
Stella ti o gbe Ni ilu eko..bi ko ti e le so, o ma gbo ede yoruba diedie.
DeleteDint understand a thing.
ReplyDeletePlease I need a good translator.
I wish I can understand yoruba eh
ReplyDeleteOmo ale jati jati. Ole. Oko mi. Iyawo mi. Edada! Omo Yoruba. Ko possible. Ekaro. Ekabo. Ekuse. Emabinu. Ermm...
ReplyDelete#WhiteDiamondOut
Hahahahahahha o dabo
DeleteWhity what did u just typed? Hohohohohi
DeleteSe Yoruba Ni e white diamond
DeleteLmao! I am 'sparking' Yoruba o.
Delete#WhiteDiamondOut
Ikpi kene itang k'iko ukang nyin, ekpa e do ikod?
ReplyDeleteI can read and understand your language Abeke but can you read and understand mine? See, why you should be considerate of other BVs.
Emi na ki e pada, Abeke. Angeli wa e seun oh, amin fun adura ti Abeke gba fun yi
Hian! Go to the Igbo post!
DeleteThat's not Igbo language
DeleteNaija Ponbele, a ki binu ori ka fi fila de furo o. Se ilu abinibi tire ni Abeke ngbe bi? Jowo dari ikanra re sodo stella, ko le gbe ipele iru eleyi naa jade ni ede ilu re.
DeleteWon ma peyin, ko ti kan yin!
DeleteIs that Annang?
DeleteAyaya
Must u guys copy? Be unique for one.
ReplyDeleteLemme call my ilaje mother. Brb
There's nothing like copy here. Stella has done this in the past. Wait for hausa version.
DeleteShut up bitch,this isn't the 1st time SDK will be doing this.Im sure Hausas are having theirs tommorow.Olorikori omo.
DeleteEverybody is trying to be relevant by abusing tribes on stella's blog o ga o. Bo ya won de un fun yin Ni ebun fun eke ebu Ni.
DeleteAyemafuge Ilaje! Awa yeeee.. Ideato u correct. Aha un re!
DeleteSoon you go begin form old bvs from jalabiya days with no memory of stella doing this post in nigerian main languages turn by turn.
DeleteStill on uniqueness and relevance. Pls remove ilaje from ur ID name, you claim to have their blood but you never hesitate to make hateful comment about them. Omo ale jatijati, akotileta.
DeleteIdeato author of confusion. O komi eshin da sile eran, komi eran da sile eshin. Abaniworan baarida, o suna sigi, sungi sina. Tori iru awa omo oodua ko o, tori awon ebi e ni. Omo irankiran!
DeleteO dabi pe ati ohun rinwa ni babe yen
DeleteStella ur Yoruba no be am😂😂😂
ReplyDeleteBawo nii eyin ara ile...
Aku dede Iwo yiii
Emi ni Omidan Ayinke Ade😘
I tried, I could actually read it.
ReplyDeleteLol, the only thing i could read and comprehend is "ĺori blog yì"
ReplyDeleteAhia ndi uka abiala.
ReplyDeleteThis comment has been removed by a blog administrator.
ReplyDeleteThis Awele is very stupid!...
DeleteOri yi ti yi sir. Nobody asked you to insult any tribe or shade any tribe, na so una dey do dey cause katakata up and down. Agbaya Jati Jati. Airhead.
Delete**Order your boxers, Singlets, socks, @ affordable rates. We deliver **
Awada e po.
Deletetesi oju e.
Nnuku pele oh,oja eeh ko ta leti awon bvs mo.Onibara,lo waye si egbe raluwe ni Agege ,awon egbe eeh wa ni be.
DeleteQueen:iya were onisekuse,shei mo ta si eh ni?Lo do oko awon omo keekeekee to mo do.
DeleteSeriously maid of this blog, that is how you always sound too that makes two of you...but I believe awele is learning where your own stupidity start from.
DeleteDid u have to be tribalistic? Oloshi oloriburuku, ikeji eku
DeleteI shouldn't have dignify you with a response. It obvious you have got serious ringworm in your brain. Alainironu
DeleteIkeji eku yeeeeeee, Eka joy ti finish maid of this blog. Kikikiki
DeleteStella delete please
DeleteHahahaha
DeleteAwele mo n gbadun e gan!
Bwahahahahaha.
Ki won gbo won ni 'gbokugbo abi?
Ki won tun te e s'oju e fun wan.
Girl yi funny sha.
Kakakakaka
Awele is only putting his or her humor to use
Deleteafter all majority of you say worst
Eka sorry dear,I know you're frustrated.
DeleteNnuku onibara,you now have mouth to talk back at people abi,ugly duckling.Like I said before get a spot at Agege railway,that's where you're colleagues are.
*your
DeleteSee this tse-tse fly. Hian. shey o ni opolo ni? Tabi o ni Arun opolo? Which one is wrong with you. U must b very stupid, talk back, I know u bfor, abi I dey fear anybody for this blog bfor? Mtcheeew. Ori yin kope rara ma. Shey u wanna b stupid, I will b your anti-stupid on this blog.
DeleteEka sun eyin eyan mi lori blog yi. Se Alafia le wa? I hope say I try btw am Igbo
ReplyDeleteKo ara eh kuro nibi,yanmirin.
DeleteIt is Ekasan
DeleteYou got the rest right
Lol.. Thanks
DeleteO gbiyanju
DeleteOmoluwabi patewo fun ara e.
DeleteThis Yoruba Bvs go sleep here today. Lool......let the comments start rolling in.....
ReplyDeleteThe way the igbos sleep on their own too I guess
DeleteAnd u're finding it difficult to stay away from the party. Omo irankiran!
DeleteTime keeper!
DeleteMay ur life be saved from i must comment spirit. Na by force to comment?
Deleteo kare stella
ReplyDeleteEkaa'san eyin eyan mi ni'bi gbogbo te tin ka bulogi yi kaakiri agbaye
ReplyDeleteOwo meji fun Iya afin Korkus fun eto yi, gbosa ogunlogan fun gbogbo angeli at'orishe ori bulogi yi
Ashejere ama je ti gbogbo wa, Olorun a ma da aabo re bo wa, Amin.
Emi ololufeyin naa ni,
SHARONNA
Sharonna baby,
DeleteGbogbo Ile nki e o
Stello olodo .why you no write (blog) for yoruba...se o wapa ,stella iyawo cockus.
ReplyDeleteEkaro oo awon beefees
ReplyDeleteEshe gon Stella
Mo ko gbo gbo ile ooo, inn Ora, inn Okun ... Ede ekiti ni mo so yen ooo. Inn ara ekiti, ati inn toku se dada lewa ooo.
ReplyDeleteOmo ekiti to gbayi 😄😃👍
Omo Ekiti ni me ha.
DeleteKe happen?
Se ala ni?
Uyan a yun lerun re.
Kare lua mí... Omo Ekiti ni me à
DeleteLara okun ooo.
Lara peperempe,mo wo'she e ju... Ori e pe bi ori alajo shomolu to ta moto to fi ra keke
DeleteOmo Ado oraaa ni mehia,awa lomo amu'kara sabe ewu je....
I'm yoruba..couldn't read the last part. Abeke! Chop knuckle.
ReplyDeleteAbeke gbogbo ile kin e, ose to gbe Ede wa laruge. Ede to lewa ju lo #tongueout#. Ede to lasa ati ewa. Eyin omo odua eku reccession yi oh, Olorun a ko wa yo
ReplyDeleteKikikiki @recession
DeleteAmin o
MrsBee
Abeke gbogbo ile kin e, ose to gbe Ede wa laruge. Ede to lewa ju lo #tongueout#. Ede to lasa ati ewa. Eyin omo odua eku reccession yi oh, Olorun a ko wa yo
ReplyDeleteEma binu, Yoruba mi baad ghan, Omo Yoruba ni mi o! Hope I've not destroyed my language? Chai! Lmao!
ReplyDeleteBawo ni gbo gbo Omo kaaro oji re bi.se ala ni se?omo ekiti nimi re ooo, inn Ora, inn Okun kete Omo ekiti Lori blog yi ooo.😄😃😃😃
ReplyDeleteStella ku ise takuntakun,olorun a San e no esan ire ooo, awon Omo e aye ooo(Amin).
Mo tun gbadun eleyi o, o dara ki a gbe awon asa wa laruge. Ko si ede ti o dara tabi ti o lewa ju ede miran lo. Yoruba ni mi, inu mi si dun gan lati je omo ooduwa.
ReplyDeleteAbeke o kare lae. Apeke loruko oriki temi ire o.
Eleyi gidi gan ooo....... Ori gbogbo wa m be
ReplyDeleteEmi o kin se omo Yoruba o. sugbon mo gbo yoruba ju elede yoruba lo. Stella oku ise takun takun, owo e ama ro ke o ni agbara olorun, olorun a si ma wa pelu e ati awon omo e and oko o, ni oruko Jesu kristi. Amin.
ReplyDeleteOzeiza omo Ebira lon kin yin pe oda bo.
O Kara lai, okan shosho ni gbogbo wa
DeleteMrsBee
Abeke, Ose omo iya mi, wa se opolopo ori re,Gbogbo omo odua, mo ki yin. Emi ni omo na biggy.paul@yahoo.com
ReplyDeleteWhere are the omo oduduwas or afonjas?
ReplyDeleteThey should get in here
O ba iya gbogbo éyin ajékuta maa momi,e sha amin kingbo
ReplyDeleteKikikikikikiki
DeleteHahahahaha.
DeleteMo gbadun post yi
Amo, emi kin se omo Yoruba.
Hahahhqhahh,in okun awe,emi eyin loju Olodumare ni moun ki yin oo,omo owor madeh
DeleteEbingba mi gan... Taloni guguru ati ekpa?😄😄
ReplyDeleteEbi npa mi lo fe so, o gbiyanju👏🏽
DeleteMrsBee
EKu se omo gbogbo aiye o
ReplyDeleteEkasan gbogbo Ile, se Dada la wa
ReplyDeleteste ste o ma try gan
ReplyDeletemo ri pe o shey biri biri bi obirin
olorun ma wa pelu E oh
gbo gbo nko ti o ba fe ki odun yii ko to pari
Olurun ma fun e sey...
gbogbo family sdk awon ti wan fe oku abi iywawo olurun a run ageli fun yii oh..
loruko jesu christi olu wa wa
eei aleluya meji
o go
ogo
ogo
Amin l'orukø Jesu.
DeleteOśe
Mon ki gbo gbo ile
ReplyDeleteAa fe ri nyammiri kan nibi o. E ma wa ba ede wa je o LMAO
Tootø
DeleteStellastico Stella, o se gan. Ku ise opolo O. Oke oke lowo re yio maa lo.
ReplyDeleteWa ri batise, wa ri ona gbegba. Oni bawon Ku iku owowo. Amin lase Edua
AMBER
Hmmm, Iya Afin Sitela eseun fun aye ranpe yi lati so ede Abinibi wa, ki okuwa ki o bukun fun yin ooo . Ara birin Abeke Ku ise na. I Dabooooo..
ReplyDeleteMo ki gbogbo ile oooo.
ReplyDeletea o ni ku ni kekere.
Odun yi o ni di wa maru lo oooo.
arabirin stella,ku ise ribiribi ti o n se ninu ile aye.
Olorun a sa esan fun e.
Awon Omo e ma ri alaanu.
mo ki gbogbo eyin elegbe mi pelu.
Iya afin linda Eze.
Iyawo Ogagu.ati beebelo.
Shakiti omo mi
DeleteGbogbo ara ni mo fi nki e
Ano M na eche this post kemgbe Ndi Igbo mere nke ha... Chaii. Ofe mmanu na copy copy. Unu bu ya na ishi. Ahubem!. Ekelem Unu ooh nu!
ReplyDeleteOmo a fi ipa ji iya ati baba re Lori ibusun a copy copy yin O.
DeleteOloriibu lo ko si konga.I can bet your smelling ass is new here.Wait for the Hausa version tommorow.
DeleteOmo a fi ipa ji baba ati iya e ki ni won un copy lara yin o
DeleteGbenu oshi soun, omo yibo!
DeleteE ri ori e bi fila
Eka joy won't see this and scold him.
DeleteOmo osan to nko ponpo ba iya e @kaycee
Bi won se ma nfori k'epe niyen.
Olofo!
Lara, eleyii ko bu Ilu yin bi awele. Abi shey copy copy tun ni ebu nla ni?
DeleteOK, on a more serious note, awele went ahead to really insult the igbos, how can u compare it to ordinary copy copy.
Or, is it cos he said ndi ofe mmanu, read up and you'd see that we were called awon aje okuta mamomi and I didn't complain about that.
Eka bitter soul keep around this post like a headless chicken .
Delete*running
DeleteMo like blog yi bajebaje, Abeke, yio dara fun o.Stella o seun o.
ReplyDeleteAbeke, oo osheeeeeee.
ReplyDeleteEku dede iwoyi o. Moki gbogbo yin lokunrin lobirin, lomode ati lagba. Inu mi dun si blogiyi mo si dupe lowo arabirin Stella aya Korkusu ni germani. Eku ise naa olorun atunbo maa ran yin lowo, osi ni shise , oju ooni tio loruko Jesu kristi . Mo tun fi asiko yi dupe lowo gbogbo angeli funi funi ori blogiyio lorun aamaa gbe owo yin soke eni sunku o. Gbogbo awon eleya meya ori blogiyi ni mo kio eje ki ife lorun ko joba laa rin wa, emase jeki ede ko ya wa, ki aye sebi Omo iya awusa. Olorun yi o duro ti gbo gbo wa o aaoni ba odun yi loo. Lati ilu morika ni motin ki yi o. Odaabo
ReplyDeleteEkasan awon inyomi
ReplyDeleteMo ki gbogbo yin o!
ReplyDeleteGbayi stella, abeke nle oo omo Oodua tooto.
ReplyDeleteBeeni oo
ReplyDeleteAwa Omo oduduwa ni a dara julo ni Orile ede yi
Ema se tele awon omo yanmiri wonyi ti won nife is ijogbon. Awa omo oduduwa lo ri bulogu yi nife si alafia. Emi je okan ninu won.
Stella, dakun se posti lori ede ilu mi, ede awon ti won ma n je eniyan, ede ore re yen to rewa daada....
Ikwakwakwakwakwakwakwakwakwakwakwa
My ofe mmanu language is on fleek, you need to hear me speak it..... Wetin dem dey call people wey sabi speak plenty language? I dey come make I go google am.
Éyin eyan mi,ni ise ni ke ló wo bulogu akant anty to wa lo ke yi pelu ti anty to fun ni owo lé ni.Opolopo akant ni enikan shosho ni lori bulogu yi.Áafe ju mewa lo
DeleteOgbon gbogbo wa ko ni baje oooo#okannioriledeNigeria
ReplyDeleteMrsBee
Mo ki yin, eyintemi!
ReplyDeleteBlog yii, ko gbø dø baję ooo
Mo ni ife to gbona felifeli fun efribody.
End time Oduduwa
ReplyDeleteOmidan Stella, oku ise ribiribi ti o n se ni ori blogi yi, Oluwa a ma so agbara e di otun. Oku itoju wa ati awon alai ni ti o n ran lowo, oju oni ti enikan kan wa oh, asi dara fun gbogbo
ReplyDeletewa o, amin! Between I'm Edo...
...Jesus is my worth!
Ewe soo dede ewen omo alaare...
ReplyDeleteMi o tí ri Sunshine nibi yi o, ibo lowa? Tori momó wipé omo yóóba toja fafa ni.
ReplyDeleteEkulé gbogbo ara ile.
Eyin omo Ekiti mofi gbogbo ara kii yin oo, iñ pele oo
ere tete ni mosa debe, uya lenu nije fun mi pe e siun konkon ko je 'pajawiri libé. Ti ede yooba to koja dun ju yee lo #inekitidialect
ReplyDeletei rushed to this place (thread), was surprise to find out that there is no emergency.D last post abt yoruba was more interesting than dis
Ale o..'Egin ma e ki won oo
ReplyDeleteSe mo ba won i ye!!...
Inumo dun lati yi beiyi oo
kikikikikikik..Who no understand!!
Eku gbo gbo lori blog yi o. Oluwa a fun wa ni itura nipati igba Buhari yi o. Ase.
ReplyDeleteSDK, eku ise takun takun lori blog yi. Mo si ki gbogbo omo Yoruba, eyin ara wa ni orile ede ati awon ti nbe ni oke okun.
Egba la wa. Ba a wa